Sango Lo Ni Sẹẹrẹ : Egungun Wizkid Laye Tẹle Ju Olayemi Oniroyin 2/19/2014 11:38:00 pm Amuludun Edit Awọn aye ti kede Wizkid gẹgẹ bi olorin Naijeria ti yóò kọkọ ni awon eniyan bi Milionu kan ti won wọ tẹle lẹyin bi ìgbà ti awon òròmadìẹ n wọ tẹle iya won lẹyin lori ẹro iwiregbe Twitter. Won ba Ọya ja lasan ni, à sé Sàngó lo ni Sẹ́ẹ́rẹ́! Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS "Ojú tí Nìyí, Toyin Abraham ti...Foto ètò ìsìnkú Aisha Abimbola nílù...Ìrántí ọdún kan Moji Olaiya wáyé lẹ... Sango Lo Ni Sẹẹrẹ : Egungun Wizkid Laye Tẹle Ju Reviewed by Olayemi Oniroyin on 2/19/2014 11:38:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment