Ẹnu ọjọ bi mẹta yii ni Davido fi ẹnu ko omobirin ajoji kan lẹnu lori ẹro instagram rẹ eleyii ti ẹnikeni ko mọ ẹni ti ọmọbirin naa jẹ. Nibayii, eégún ti mbẹ ninu ẹ̀kú ti pada foju han sode. Faith Nketsi ni omobirin naa njẹ, omo ilu South Africa ni i se. Won ni omo naa gbera lati ilu South Africa wa si ilu Naijeria lati wa lo Ayajọ Ololufẹ pẹlu ọrẹkunrin rẹ, Davido.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment