Smiley face

Won Sa Okunrin Onitiata Naa Yamayama: Isẹ Tiata Isẹ Ọpọlọ

 
Saheed Osupa ti kede fun gbogbo araye lati ọjọ to ti pẹ wi pe isẹ tiata kii se isẹ ere lasan, Oba orin sọ wi pe isẹ ọpọlọ gidi ni. E wo ohun ti awon asarologe so Emeka Enyiocha da. Fiimu tuntun ni eleyii ti won ya lọwọ, akole fimu naa ni Blood is Money.






Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment