
Baalu oko ofurufu ti awon omo ologun ti ilu Algeria ti jalule ni ori oke kan ti n je Djebel Fertas to wa ni Ariwa-Ila oorun ilu naa. Oko ofurufu to kun fun awon omo ologun ati awon ebi won (iyawo ati awon omo) yii ni won lo segbe latari kurukuru to bo oju ojo mole ni agbegbe naa. Awon eniyan bi metalelogorun (103) ni ile ise iroyin BBC se alaye re wi pe won ba isele naa lo nigba ti won ti ri enikan soso to wa laaye ninu awon ti ijamba oko ofurufu naa sele si.
0 comments:
Post a Comment