Smiley face

Ololufe Ma Da Mi

Ololufe Ma Da Mi   
Boo ba da mi,

A dun mi bi igba omi se ẹja jina

Sebi omi atẹja jọ mulẹ̀ ọdadamada nílẹ̀ kan naa ni


Ololufe ma da mi

Boo ba da mi,

A dun mi bi ìgbà ehín rẹju ahọn jẹ

Sebi ehin atahọn, ọ̀kan nilé ti wọn


Ma je n parọ tan ọ, ololufe mi.

Iwọ lokan ifẹ ti mo fi n mi
Iwọ lojú tí mo fí ń ríran nígbà gbogbo.
Iwọ si ni ìyè ti kò jẹ ki n ku sara bi eniyan lasan.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment