Smiley face

Orisi Irun Ori Tuntun Mario Balotelli Tun Jo Aye Loju

 
Igba ti mo wa ni kekere lo wu mi ki n di olokiki agbaboolu nla. Ero mi ko pe meji rara ju lati maa je iru aye ti awon agbaboolu n je lo. Sugbon ori ni gbogbo nnkan laye ni mo fi ko buutu mi danu.

Yato si aye jije, awon agbaboolu feran oge sise. Omo agbaboolu AC Milan, Mario Balotelli ti lo pada serun oge tuntun eleyii to lekenka.

Orisi sitayi irun eyi tun 'nautical'.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment