Smiley face

Eemo: Omo Odun Meji Ti N Fa Siga Bi Agbalagba



Fidio omo yii ti wa lori ero YouTube bayii, o si je ohun to jo olopolo loju lati ri omo kekere ti ojo ori re ko ju meji si meta lo ti n fa siga bi agbalagba ti siga mimu ti jingirin mo lara.

Ninu fidio yii, bi omo yii se n fa siga doo bee naa lo n tu efin dudu soke lala lai wuko.

Awon eniyan sakiyesi wi pe oseese ko je ilu Finland ni aworan naa ti wa ati wi pe omo naa ni lati jogun iwa buruku bee yala lowo awon obi re tabi alamulegbe re.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment