Morenike n fura si ọkọ rẹ wi pe o ti n ni ajọsepọ pelu ọmọ-ọdọ won ti n ba won toju ile ati awon omo. Ati wi pe o kofiri wi pe o seese ko je wi pe o maa n yo lo si yara omo-odo won loganjo oru. Morenike ronu ọgbọn lati mu oko re lorun owo.
Ojo kan ni Morenike da bi ogbon lo ba ran omo-odo won nise lo si ọdọ iya rẹ to wa ni ilu odikeji lai je ki enikeni mo sii. Igba to di loru, Morenike yọ dide lẹgbẹ ọkọ rẹ lo ba lo sun si yara omo-odo pelu aso ibora to yi mọri. Iseju bi marun-un sigba ti Morenike ti rẹkẹ kalẹ ni enikan yọ wọ inu yara naa. Morenike pirọrọ lai mira nibi to sun si. Eni to wole ba mọ Morenike lẹgbẹ laisọrọ. [Inu okunkun ni awon mejeeji wa]. Igba to ya ni eni to wole n fi owo ra Morenike lara, bayii ni won se bere ti won fi n ba ara won ni ajosepo.
Won se ọwọ kinni, won se owo keji, sibesibe ara jagunlabi si le sibe lati se owo keta. Gbogbo bi won se n sere ni Morenike finu sepe fun ọkọ rẹ.
"Olori buruku okunrin, mi o gbadun re bi eleyii ri, tipatipa la fi nse owo kan delẹdelẹ. A se ibi lo ti wa n lo gbogbo 'energy'."
Morenike n sọrọ sinu bee ni won sere ife lo ti awon mejeeji si n laagun yọbọyọbọ bi adiye keresimesi.

Ọkọ ti wo gbogbo ile ko mọ ibi ti iyawo re wa. Gbogbo yara lo wo ko mo ibi ti iyawo re wọle si loganjo oru. Igba to ya lo lọ se abewo si yara ọmọ-ọdọ. Ninu yara omo-odo lo ti ba iyawo re, Morenike ati Audu gate-man nibi won ti n se wamọwamọ.
To ba je wi pe eyin ni oko, nje e le gba iyawo yin gbo?
To ba je wi pe eyin ni iyawo, kini e fe so fun oko yin?
E ba wa dasi...
To ba je wi pe eyin ni oko, nje e le gba iyawo yin gbo?
To ba je wi pe eyin ni iyawo, kini e fe so fun oko yin?
0 comments:
Post a Comment