Smiley face

Tiwa Savage Ti Wo Gau: Eminado Ti Daran Olopa


Awon Olopa ti gbe omobirin olorin ti oruko n Je Tiwa Savage ni aaro oni yii ni iwaju ile itura Eko Hotel to wa ni ilu Eko.

Okunrin olopa ti n se ise alamojuto lilo-bibo oko lo da moto omobirin olorin naa duro. Oro ti oga 'Yello Fifa' so lo fa ibinu, ibinu yii lo mu Tiwa si fila lori olopa lo ba si se bee so fila olopa sinu gota.

Awon olopa ti mu omobirin naa lo si ago won bayii.

#KosiEniKojaOfin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment