Smiley face

Asiri Boko Haram Ti Won Fe Ju Bombu Si Soosi TB Joshua Tu


Awon omo Boko Haram gbiyanju lati ju bombu sinu Synagogue Church Of All Nations lonii sugbon asiri won tu nigba ti ojise Olorun TB Joshua fi emi Olorun gbadura pelu agbara. Awon merin ni awon omo Boko Haram ti won ran ni ise iku naa, sugbon lojiji ni ede won daru pelu iberu okan, awon meta salo nigba ti okan ninu won ti n je Mustapha lati Ipinle Adamawa wa jewo ise ibi won ni iwaju Oluwa.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment