Bi iro ba lo logun odun, awon Yoruba ni ojo kan pere bayii ni otito yoo ba. Oro lori Papa Tosibe ti won lo fi tipatipa ba Olanike Olaiya sun ti pada di ohun to feju ti gbogbo eniyan si ti wa mo ododo oro bayii. Arabirin to mu Olanike Olaiya mo Alh Abass so wi pe iro ni gbogbo ete Olanike Olaiya. Ogbon ati lu Papa Tosibe ni Jibiti Milionu Mewaa (10M) lo n da nitori oun mo si gbogbo ogbon re lati ibere pepe.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment