Awon amokunseka kan ti seku pa awon eniyan bi mokandilaadorin (69) ni awon agbegbe bi merin kan to wa ni Ipinle Kastina.
Sebi awon Yoruba lonii oru laa seka, eni ba se iru e losan ko ni fi ara ire lo. Sugbon owe yii ko ba isele to sele ni ilu Kastina lo rara pelu bi won se seka osan ti won si lo pelu alaafia.
Osan pon ganriganrin Ojoru ose yii ni awon kan ti won je awon eya omo Fulaani yawo Mararaban Maigoro, Goran Mota ati Ungwan Rimi pelu okada ti won si bere si ni yinbon lu awon eniyan agbegbe naa.

Nibayii, Aare Goodluck Jonathan ti fi awon omo ogun ranse si ilu naa lati lo finna mo awon eniyan ibi naa ki won si wa won jade mi kiakia.
0 comments:
Post a Comment