Smiley face

Awon Olopa Ri Ori Eniyan Ninu Baagi Ni Ipinle Ogun


Owo awon olopa Ipinle Ogun ti ba okunrin kan ti oruko re n je Adelani Ayomide eni ti won ka ori eniyan bi mejidinlogun (18) mo lowo ni oju ona Owode to wa ni Ad-Odo.
 
Gege bi a se gbo, omokunrin ti ojo ori re je mejidinlogoji (38) ni won gbamu lOjobo ose yii nibi ti awon olopa ti n da moto duro fun ayewo ni agbegbe Ado-Odo to wa ni Ipinle Ogun.
 
Agbenuso fun oga olopa Ipinle Ogun, Ogbeni Muyiwa Adejobi lo so eleyii di mi mo fun awopn oniroyin. E gbo bi okunrin naa se salaye isele naa:
 
 
"Adelani Ayomide,38, of Ilaro, Ogun State, was arrested today, March 13, 2014, at about 6.48am by policemen attached to the Ado-Odo division while on stop and search along the Ado-Odo Owode Road.
 
"The policemen caught him with one bag containing 18 human heads. The suspect will be transferred to the State Criminal Investigation Department, Eleweran, Abeokuta for further investigation."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment