Ariwo gbale-gboko, sunkere-gbakere kun gbogbo oju titi oloda, afihan ola ati igbelaruge ise opolo to fakiki sele ni ilu Ibadan nigba ti awon irawo osere wo Ipinle Oyo fun ayeye Yoruba Movies Academy Awards (YMAA) eleyii to waye ni Ibadan Civic Centre Agodi, Ibadan.
Orisiirisii osere ori itage ati awon gbajumo lagbo amuludun ni won peju pese sibi ayeye to waye lojo Aiku to koja yii. Lara won ni Lere Paimo, Jibola Dabo, Mercy Aigbe, Iyabo Ojo, Saidi Balogun, Yemi Solade, Hafiz Oyetoro (Saka), Olaniyi Afonja (Sanyeri), Otunba Kola Olootu ati bee bee lo.
A tun maa se afihan awon aworan to ku laipe.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment