Smiley face

'Awon Obayeje Ti Le Mi Kuro Lori Facebook' - Stella Damasus

Oserebirin Stella Damasus ti pinnu lati fi ori Facebook sile patapata latari awon obayeje ti won fi oruko re lu awon eniyan ni jibiti. Nibayii, omobirin naa ti kede wi pe oun ko si lori Facebook mo. Bakan naa lo tun fi kun un wi pe nibikibi ti won ba ti gbo nipa Stella Damasus lori Facebook ki won mo wi pe awon obayeje eniyan ti won pe ni 419 ni.

Ki eku ile ko gbo, ko so fun to ko. Ki adan o gbo ko ro foo obe.

Olayemi Oniroyin, se mo wi i re tabi mi o wi i re?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment