Awon omo ogun Boko Haram ti leri ninu leta ti won ko si awon omo ologun to wa ni Ipinle Borno lati yalu bareke omo ologun Iko Keje (7th Division) ti Maimalari Barracks loni Ojo Eti (21/3/14).
Ti a ba lo so wi pe iro ni oro naa to ba lo je otito nko? Idi niyi ti awon omo Ologun ile Naijeria fi lo wo ewu ogun ti won si n bu ramuramu wi pe aja to ba wole ekun yoo fi eje we ni ti awon omo Boko Haram ba file yoju si bareke awon lonii.
Enikan to ko lati daruko ara re lati inu bareke naa lo salaye leta ijaya ti awon Boko Haram yii ko ranse si awon omo ologun. Alaye re ni yii:
"Yesterday, the Boko Haram sect wrote that they would attack the Maimalari Barracks. They wrote
the letter in Hausa Language to give the notification of their coming.
"However, security operatives are praying for them to come to the barracks. The barracks is the biggest; it is the cantonment in Maiduguri.
"The barracks accommodates, the 7th Infantry Division, the Artillery, Ordinance, Engineering, Signal and other corps.
"People are even surprised how they got the letter to the barracks; one cannot rule out intimidation of one of the drivers to get the letter to the barracks.
"Soldiers are on the red alert. There are many soldiers there who are waiting for the attack. Soldiers are battle ready,"
Ninu ero mi, ko ma lo je wi pe oto nibi ti awon Boko Haram fe ti se ise ibi won to je wi pe ogbon ati si awon omo ologun niye ni leta won da le lori. Ju gbogbo re lo, Oosa Oke ko ni fi wa sile fun ota mu.
E ku Jimoh!
Home / Uncategories / Asotele: Awon Boko Haram Maa Yalu Ibuba Awom Omo Ologun Lonii Ojo Jimoh Ni Ilu Maiduguri
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment