Awon omo Boko Haram tun ti pa awon eniyan bi mokandinlogbon ninu oja Nguro-Soye ti ko jina si Bama ni Ipinle Borno.
Ale ojo Abameta to koja yii ni agbo wi pe won ju ado oloro iku naa eleyii to ra awon alaise lo sorun apapandodo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment