Smiley face

Itan Liatu Ati Janet Lati Inu Igbo Boko Haram Ni Ipinle Borno

Odun ti Ayinla Omomura lo si ilu Mecca to dari dele, orin tuntun ni ogbontarigi olorin apala naa fi ki awon ololufe re kuule. Ninu awo orin naa lo ti n wi pe:

'Mecca alalobo ni ti wa oo
Mecca alalobo ni ti wa
Eni ti o royin ogun ko ni ku
Ayinla re Mecca o bo oo
Mecca alalobo ni ti wa.'


Bee gele lori pelu Liatu ati Janet ti won ti wa ni igbekun awon omo Boko Haram ko to di wi pe ori ko won yo.

Oniroyin ile ise BBC, Will Ross lo se alabapade Liatu ati Janet. Awon Omobirin naa si salaye gbogbo ohun ti oju won ri ninu igbo irumole ti won gbe won pamo si, nibi ti won ti n dun-unbu eniyan bi eran ileya.

Liatu eni odun metalelogun(23yrs) lo side iforowero naa pelu Will Ross, e gbo ohun to wi:

"They asked me if I am Christian or Muslim. I said I am Christian,"

"On the 11th day [ninu igbekun], they brought a man to me and said that he liked me and I should convert to Islam so that he can marry me."


Gege bi oro Liatu, o ni lodun to koja ni awon onise ibi naa wa da awon lona ti won si pa gbogbo awon osise ijoba ti won je Musulumi loju ese nigba ti won ko awon yoku lo si inu igbon Sambisa to wa ni Ipinle Borno lati lo se won sikasika.


"They were slitting people's throats with knives. Both women and men were killed - especially the
men who didn't agree to fight for them,"


"Those that tried to escape were shot but they hardly ever used their guns to kill. They usually used knives. About 50 people were killed right in
front of me."

Gbogbo igba ti Liatu fi wa ninu igbo pelu awon Boko Haram yii, omobirin naa salaye wi pe oun kii jeun ati wi pe awon omo Boko Haran naa n gbiyanju lati so di iyawo.

Sugbon lojo kan ni okan lara awon eniyan ti won jo wa ninu igbekun Boko Haram gbiyanju lati sa, oun naa si pinnu ati te le won.

'Sebi ojo kan ni eniyan n ku.'

"One of the captives stood up and said: 'You only die once. Who is ready to make a run for it?' Six of us jumped into one of the Boko Haram vehicles in
the camp - a Volkswagen Golf."


"They chased us on motorbikes, shooting at the car until we got close to Bama town. Then they left and we got out of the car to continue on foot
as there was a curfew in place. It was only then that I realised the three people on the backseat had all been shot dead."

ITAN Janet

Odin-indi osu meta ni Janet omo odun mokandinlogun (19yrs) fi wa ninu igbekun awon Boko Haram nibi ti won ti n gbiyanju lati so di apaayan.

"They went to Gwoza and brought five people to the camp. They started slaughtering them in front of me.

Then they ordered me to slit one of their throats. I refused. I told them I couldn't do it. Then the wife of the leader of the group killed him instead."

Gege bi alaye Janet, oni pupo ninu awon omo Boko Haram naa ni oun mo to je wi pe omo adugbo ni won je.

"I knew almost all the people in the group I was with. I knew them from my home area," Janet

"I was really angry and when I couldn't keep quiet any longer, I said to one of them, 'When we were at home you would even visit me and I
respected you. So why are you doing this to me?'"

E je ki tun pada sinu iwe iroyin Punch lati lo wo ki ni ero awon eniyan nipa Itan Liatu ati Janet.

E gbo ohun ti awon eniyan so:

Danalkali
Very interesting story. Liatu and Janet should thank their stars for surviving to tell this pre-arranged stories. May God help us in Nija amen.


Jefia
"She said she recognised the faces of the men who held her captive as most of them came from her area.

Janet said, "I knew almost all the people in the group I was with. I knew them from my home area."

Nijeriyans keep on deceiving yourself about Boko Haram! The Northern leaders know everything about Boko haram yet they refuse to stop it!

These leaders are seeking Political
gains to unseat Jonathan and using their people as pawns in this wicked game!!

I don't know if Nigeria will truly survive beyond 2015!!!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment