Smiley face

D'banj Ti Fe Le Gaari Ijebu Wole Pelu Koko Garri

D'banj ti se ifilole Garri re eleyii to pe ni 'Koko Garri'. Koko Garri ni akanse gaari igbalode ti won ti pon sinu ora pelu ara otun eleyii to mu gbayii ju Garri iya Silifa onigaari Ijebu lo. Koko Garri ko ni pe wa ni awon ile itaja igbalode kaakiri tibutoro ile yii.

Yato si wi pe D'banj n korin, agbe oloko tun ni. Lara ere oko re naa ni won ti gbe Koko Garri jade.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment