Bi ko tile si lori oye mo, aye oloba Orji Uzor Kalu to je Gomina Ipinle Abia nigba kan ko duro rara. Joojumo ni i fi eja tutu mu otin waani pupa leti odo. A tile gbo wi pe aye ti okunrin naa n je ko kere rara eleyii ti ko tile rije nigba to wa lori oye gan-an ni fi n se faaji ara. Bee si ni bisineesi re ko duro pelu ise agbase lorisiirisii to tun mu owo wole lojoojumo. Olayemi Oniroyin, mo ki yin kaaabo sinu aafin aragbayamuyamu Orji Uzor Kalu eleyii ti mo pe akole ri ni AJEKULAYE GOMINA WA. Erkk
Orji Uzor Kalu n fi owo si ise agbase tuntun
Orji Uzor Kalu pelu amugbalegbe re
Orji Uzor Kalu n jiroro pelu eebo agbase se
'Aye mi ni mo n je, mi o jaye alaye'
Orji Uzor Kalu pelu awon oga osise alaabo re
Orji Uzor Kalu pelu awon oluranlowo re
Orji Uzor Kalu pelu awon igbimo ti won wa ba lalejo ninu agbala re
0 comments:
Post a Comment