Smiley face

Igbeyawo Awon Omo Oba Fuji

Idaya ati Bismillahi Quawiy

Edumare fun wa lomo ti yoo yan ti yoo yanju. Idunnu nla lo je fun Oba fuji lati se igbeyawo awon omo re obirin meta tele ara won ni igba kan naa ni inu ile nla re to wa ni Ijebu Ode. Idaya lo se lojo Kerin osu keta nigba ti Ameenat se ti e lojo Kefa osu kan naa nigba ti Sekina se tie lojo Kesan-an osu keta odun 2014. Adura wa ni wi pe Edumare yoo fi adun si ebi tuntun awon omo meteeta won yii. Amin
 
Ameenat ati Hakeem Lawal
 
 
 
Eto Igbeyawo Sekinat at Ademola Adeyemo beere lati ibi



 

 
 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment