Smiley face

'Ise Asewo Ni Mo Fi N San Owo Ile Iwe Mi'- Osere Fiimu Onihoho

  
Omo ile iwe Duke University ti oruko re n je Miriam sugbon ti won mo gege bi Belle Knox ni omo ile iwe re kan kofiri re ninu fiimu onihoho ni o ba tu asiri re fun gbogbo aye. Ka to seju pee iroyin naa ti gbalegboko. E tesiwaju...

Omobirn naa ba ku pa itiju ti lo ba jewo idi pataki to fi n se ise asewo onihoho. Omobirin eni odun mejidinlogun (18) naa salaye wi pe ise asewo ti oun se ni oun fi n san owo bi  egberun lona ogota owo dollar ($US60,000/N9.6m) gege bi owo ile iwe oun. 
To ba je wi pe eyin ko ti ri oro omo naa ka nipa wi pe kilode to fi yan ise fiimu onihoho laayo, ohun ti Miriam wi ni yii:


''People often ask me this question. However, the answer is actually quite simple. I couldn't afford $60,000 in tuition, my family has undergone significant financial burden, and I saw a way to graduate from my dream school free of debt, doing something I absolutely love. Because to be clear: My experience in porn has been nothing but supportive, exciting, thrilling and empowering.
The next question is always: "But when you graduate, you won’t be able to get a job, will you? I mean, who would hire you?" I simply shrug and say, “I wouldn’t want to work for someone who discriminates against sex workers.
I am not ashamed of porn. On the contrary, doing pornography fulfills me. That said, I vehemently want to have my privacy respected -- and I ask that anyone who knows my real name respect the fact that I am only discussing this publicly because it was made a public matter when I was confronted by a fraternity member who chose to tell hundreds of other men in the Greek scene.
You want to see me naked. And then you want to judge me for letting you see me naked. Today, I am choosing to reveal my porn identity to the world. My name is Belle Knox, and I wear my Scarlet Letter with pride.” 
Miriam lenu ise aje re
Bi o tile je wi pe oro naa ba awon obi omo naa lojiji, sugbon ko si ohun ti won fe se si mo, nitori omo naa ti jingirin ninu ise onihoho ti n se.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment