Edumare nikan lo mo ibi ti eda o ti gbe la laye, ohun ti kaluku yoo si je ko ni salai je laye. Omokunrin alawada ti oruko re n je I Go Dye ti fee pari ile re eleekeji eleyii ti awon eniyan n se apejuwe ile naa bi aafin oba. Ile naa ti fe e pari bayii, ilu Benni si ni ile nla naa wa.
E tesiwaju lati wo aworan ile naa...
Aworan bi ile naa yoo se ri lo wa ni isale yii nikete ti won ba pari re tan. Se e ri wi pe nnkan ju nnkan lo. Eniyan ko le fi ehin Hausa ti fi n je gooro we ehin lasan. Nnkan ju nnkan lo!
0 comments:
Post a Comment