Smiley face

Iyawo Tuface Ti De Lati Ilu Amerika Pelu Idibia Ni Igbaaya Re

Annie Idibia  lo bimo si ilu Amerika o si ti pada de pelu ayo ati alaafia. Ohun tuntun ti omobirin naa tun gbeyo ni bi o se tattoo oruko oko re 'Idibia' si igbaaya re.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment