Iyawo ile Abass Akande ti fi aidunnu re han pelu
iwa palapala eleyii to di ohun ti oun ati ale re jo n fa mo ra won lowo eleyii ti iyawo re se alaye re gege bi ohun idoti ti ko ye ki won ka mo eniyan lowo. Bo ba tile je wi pe iro ni omobirin ti oruko n je Olaiya pa mo Alh Abass Akande nipa esun ifipa ba ni lopo sibesibe nnkankan jo da won po bi eni yan ara eni lale eleyii ti ko si iyawo ile to le gbo iru iwa bee pelu oko re ti inu re yoo dun si. Abass akande gba wi pe ohun se iyawo re, o si ti bere si ni toro aforijin. Gege bi oro Omorapala nigba ti o n ba awon oniroyin soro;
"Iyawo mi Abike ti n binu si mi, emi loko re dandan si ni ko darijin mi nitori mo gba wi pe mo jebi''
![]() |
Ile Obesere Nibi To Ti Ba Olaiya Sun |
0 comments:
Post a Comment