Bo ba je wi pe saaju igba yii ti Mercy Johnson ba ri maalu yoo sa lo ni lai duru mu baagi re, sugbon nigba to ti doro ise aje dandan ni ko sebi eni wi pe oun ati maalu ti jo wa tipetipe. Ise aje lagbara, ki Edumare fi ise wa pon wa le ni adura ti wa. Amin .
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment