Smiley face

Jeju Love Land Ni Won Ti N Ko Nipa Ibalopo Ni Ilu South Korea

Awon Yoruba ni airin jina lairi abuke okere, ti eniyan ba rin titi yoo ri bi ti won ti n fi odo ibile jeun. Ibi kan mbe ni ilu South Korea ti won ti ko awon eniyan nipa ibalopo ako ati abo. Jeju Love Land ni won pe ibi a n soro re yii, o si wa ni Erekusu Jeju (Jeju Island) to wa ni ilu naa. Yato si awon fiimu ti won fi n se idanileko ibalopo ako ati abo, orisiirisii ise ona (scultures) lo wa nibi eleyii ti n se afhan ipo ti awon eniyan wa nigba ibalopo
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment