Gongo so ni ilu London nigba ti toko-taya, Beyoncé ati Jay Z ti leri orin agbara fun won ololufe won ti won si mu gbogbo ileri won se pata lojo Isegun to koja yii. Pupo lara ijo ti Beyoncé jo lojosi nibi ami eye Grammy to da 'wahala' sile tun pada ji dide loju agbo nigba ti omobirin eni odun mejilelogbon naa fi idi jo rainrain bi okoto.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment