Smiley face

Beyonce Tun Pada Wo Ilu London Pelu Agbara Orin Ife

Omobirin onkorin ilu Amerika, Beyonce Knowles ti bere iyide orin si awon ilu to wa ni Europe eleyii to pe ni Mrs. Carter Show World Tour. Ojo Isegun to koja yii lo bere iyide orin naa pelu bo se sere fun awon ololufe re to wa ni ilu London.






Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment