Nnkan bi odun meta seyin ni Sarah Beal to je eni odun metalelogoji (43) se akiyesi wi pe
ti oun ba fi owo yun ara, oju ibi ti o fi owo yun ni ara re yoo si bere si ni le. Sugbon leyin bi ogbon iseju si wakati kan, ara re yoo tun pada si bo se wa tele. Awon onimo isegun ti se apeere iru aisan bayii gege bi ohun ti won pe ni Dermatographia.
ti oun ba fi owo yun ara, oju ibi ti o fi owo yun ni ara re yoo si bere si ni le. Sugbon leyin bi ogbon iseju si wakati kan, ara re yoo tun pada si bo se wa tele. Awon onimo isegun ti se apeere iru aisan bayii gege bi ohun ti won pe ni Dermatographia.
Agbaoje kan lati Mayo Clinic ti se alaye ohun ti Dermatographia je:
'Dermatographia is a condition also known as skin writing. When people who have dermatographia lightly scratch their skin, the scratches redden into a raised wheal similar to hives. These marks usually disappear within 30 minutes.
The cause of dermatographia is unknown, but it can be triggered in some people by infections, emotional upset or medications such as penicillin.
Most people who have dermatographia don't seek treatment. If your signs and symptoms are especially bothersome, your doctor may recommend allergy medications such as diphenhydramine (Benadryl).'
Ni aye atijo, eniyan ti won koko kola fun, ika ni won fi se fun un. Igba to ya ni ila kiko di ohun ti gbogbo aye fi n soge. Bi o tile je wi pe aisan ni Dermatographia sugbon o ti pada so Sarah di Ayaworan si ara re eleyii ti gbogbo eniyan n pe e wo to so di olokiki.
Omobirin to wa lati Arley to wa ni Warwickshire naa salaye nipa ara re:
‘My skin is so sensitive that sometimes even clothes can feel uncomfortable,
‘I can scratch my arm or my back and long lines will come up.
‘But being able to draw on my skin is so cool – it’s my party trick. The Etch A Sketch comparison is pretty accurate, although I wish a good shake was enough to get rid of the itching.’
0 comments:
Post a Comment