Smiley face

Won Ti Kede Papako Ofurufu Baalu To Dara Ju Fun 2014

Papako ofurufu Changi to wa ni ilu Singapore ti gba ami eye papako ofurufu baalu to dara ju lo lagbaye fun odun 2014. Eleyii ni won kede ni ilu Spain ni Ojobo to koja yii nibi ti papako ofurufu Changi ti gba ami eye naa fun igba karun-un ati igba akoko ti papako naa yoo maa gba ami eye naa fun igba meji telera won.
 
 
Awon eniyan bi milionu mejila ni won dibo kaakiri agbaye nipa iriri won nipa awon papako ofurufu ko to di wi pe won kede Changi gege bi olubori papako ofurufu to fakoyo ju lo.
 
 
E gbo ohun ti awon ojogbon so nipa papako ofurufu naa:
 
"Winning this prestigious award for the second year in a row, Changi Airport Singapore is showing itself to be much more than an airport," Edward Plaisted, chief executive officer of Skytrax.
 
 
"Changi Airport offers a travel experience in itself and continues to develop its quality standards to be named the world's favorite airport again. Changi Airport is a well-known leader and innovator for the airport industry and genuinely delights and surprises travelers who are lucky enough to enjoy the airport facilities. Changi Airport demonstrates how to make the airport experience an enjoyable part of the journey that is so important in today's fast-moving world," Plaisted.
 
 
Ami eye onibeji ni Changi gba pelu bo se tun gba ami eye papako ofurufu to ni ohun elo amayederun ju lo ni agbaye eleyii ti won pe ni Best Airport for Leisure Amenities.
 
Olayemi Oniroyin, ibi ti mo de re e ti mo fi pada ni ilu Singapore.
E ku isinmi oni.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment