Okan ninu awon ololufe Olayemi Oniroyin ti n gbe ni ilu Abeokuta lo fi awon aworan yii ranse si wa nipa ojubo awon onise ibi kan ti won n fi awon eniyan gunse owo ni agbegbe Adigbe eleyii ti asiri won tu lonii.
A gbo wi pe okunrin onise ibi naa ti sa lo mo awon olopa lowo bayii. Sugbon won ri aworan re ninu ile ti okunrin naa n gbe. Iwadii si ti bere ni rebutu.
E ku oju lona fun iroyin lekunrere!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment