Smiley face

Wahala Ni Ibadi Mi Maa N Da Sile Nigboro Aye- Oserebirin

Sebi eni to wu Edua oke ni i gbega, odun 2010 ni Evia Simon bere fiimu agbelewo ki Edua Oke to baa fi alubarika si i. Aimoye fiimu lo si ti kopa ninu re.

Gege bi oro re, oni ewa ti oun ni wa lara nnkan to silekun fun ohun nipa ise fiimu Nollywood. Yato si eleyii, o ni ibadi oun ki i ye e ya awon okunrin ni were ti won ba fi oju kan oun. Gege bi iriri re, oni okunrin kan ti paaki moto re si oju titi ri to si tele oun wo inu taxi tori ko le ba oun ni gbolohun papo.


Sugbon ju gbogbo re lo, Evia Simon so wi pe owo ko je koko si oun bi ko se ife otito.

" I am not the type of girl who is only interested in money. I believe in love. To me, love comes first. I hate to have anything to do with a guy because of his money. I can stand love and bear
anything that comes with it but as for money I can't stand everything that comes with it, because I hate it when someone makes me believe I am getting close only because of his money".

Aye Irawo Osere Fun Toni Niyi. E Ku Isinmi.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment