Pelu akiyesi awon ologbon aye ti won mo nipa eto oro aje agbaye, won ni o seese ki ile Nigeria pada di bi ti aje yoo pada gunle si eleyii ti yoo mu je oga Ilu South Africa ti gbogbo agbaye mo tele gege ilu to derun julo ni ile adulawo.
Ise iwadii won yii lo gunle ikede ti minisita fun eto isuna owo ti Naigeria se, eleyii to se apejuwe idagbasoke bi ida aadorun to ti de ba eto oro aje ile Nigeria ti a ba n so nipa foonu alagbeka, imo ero igbalode (IT), eto irina ofurufu ati fiimu agbelewo ti a mo si Nollywood.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment