Smiley face

Awon Adigunjale Ba Omo Ati Iya Sun Loju Kan Naa Ni Ilu Eko

Ijamba adigun jale nla kan waye ni agbegbe Mushin to wa ni ilu Eko lojo Aje to koja yii nibi ti awon igara olosa bi ogota ti ya wo agbegbe naa ti won si se awon eniyan ibe sakasaka pelu moto bi ogbon ti won dana sun.
Aimoye dukia bi owo, foonu, goolu ati nnkan meremere ni won tun jigbe salo pelu.

Alaye okan ninu awon eniyan agbegbe naa ti isele naa ka mo inu mosalaasi nibi to ti n se asalatu ni yii:

"It was around 12am on Monday morning that we started hearing gunshots. It lasted for about an hour.
"Around 1am, they started going from house-to-house, robbing the occupants.
They stole about seven laptops from the house opposite this mosque. They stole phones, money and everything they saw.
They came inside the mosque and took our phones and money. People were crying throughout the night. It was terrible."

Lara alaye ti a tun ri gba mu ni wi pe awon ole naa fi ara bale sise owo won ni, ati wi pe nnkan bi ago mefa si meje idaji ni won to kuro ni agbegbe naa lati nnkan bi ago mejila oru ti won ti gbe ori wole.
Ogbeni Kasali Daramola to je awako naa fi edun okan re han pelu omije kikoro to n jade loju re nigba to n ba awon oniroyin soro:

"This is the third time they will do this to me. What have I done to them?
The first was a Lexus car my younger brother bought for me, which I was planning to sell to acquire a commercial bus to take care of my four kids and wife.
I sold the scrap for N30, 000. I used the money I raised to get a bus and I was paying for it by installment. I have not finished the payment when they destroyed it."

Gege bi alaye Daramola, yato si wi pe awon adigunjale yii ja won lole pelu dukia won ti won dana sun, won tun ba awon obirin won ni ajosepo tipatipa eleyii ti o ba ni lokan je pupo.

Daramola tun tesiwaju ninu alaye re wi pe awon gbiyanju lati pe awon olopa alaso dudu sugbon ohun ti won n wi naa ni wi pe awon mbo.

"For over five years now this area has not known peace. Will the police say they cannot do anything about it?
Around 7am that policemen came here, they still saw some of those robbers around, but did not do anything.
Why? I believe the police know all the people causing trouble here and if they want to do something, it doesn't take them anything."

Awon oniroyin gbiyanju lati ba alukoro awon olopa agbegbe naa soro nipa isele naa sugbon ohun ti won n wi naa ni wi pe awon yoo kan si won pada lai wi ohunkohun di akoko ti iroyin yii fi jade.
Awon moto bi ogbon ni awon ole yii dana sun, won ba iya ati omo sun loju baba won, won si ko owo ati dukia ti enikeni ko ti le so iye ti won to ni New Balogun, Euba, Ayonuga, Tiamiyu,
Haruna, Ereko, Oyedele streets ati Coker Lane.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment