Smiley face

Abiamo Ti Pa Omo Re Je Ni Uyo

Arabinrin Ita Okokon ti gbogbo eniyan mo si Iya Isaaki lo ti fi owo ara pa omo re ti n je Isaac eni odun meedogun (15yrs) ni agbegbe Atai Obio Offot to wa ni ijoba ibile Uyo ni Ipinle Akwa Ibom.

Gege bi eni ti isele naa se oju re se so, o ni iya Isaaki lo n ba omo re wi, kaka ki omo gbo ibawi lo ba ti iya re danu.

Omidan Ekaette Effiong ni eni ti isele naa soju re, ohun ti obirin naa so ni yii:

"When Isaac hit his mother that hard, the woman felt humiliated. When she got up, she went inside the house and brought out the machete. She chased her son with the machete,
but when she could not get him, she threw the machete at him, which cut through his body."

Igba ti Isaaki subu lule ti eje si bere si jade lara re ni awon eniyan adugbo ati iya re gbe lo si osibitu. Sugbon Isaaki pada ku, a si gbo wi pe iya re ti salo bayii ti enikeni ko si le so ibi to wole si.

Alukoro awon olopa ti Ipinle Akwa Ibom, Ogbeni Mr. Etim Dickson jeri si isele to waye naa.

"For now nobody has given us information about the whereabouts of the woman. We have sent in some detectives around the area to look for possible clues that can lead to the arrest of the woman."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment