Smiley face

Egbe Agbaboolu Manchester United Ti Da David Moyes Pada Si Abule

Egbe agbaboolu Manchester United ti da olukoni ati alamojuto egbe agbaboolu naa, David Moyes duro lenu ise leyin osu mewaa to ti bere si ni tuko egbe Man U.

Awon ti Old Trafford labe alase Ed Woodward to je igbakeji alaga egbe naa so wi pe olose ni maanu naa ati wi pe ko maa lo si ile re.

E maa gbagbe wi pe Sir Alex Ferguson lo fa David sile lati maa ba ise lo leyin odun merindinlogbon (26yrs) ti Alex fi se aseyori olusakoso egbe naa.

Wayio, won ti fa egbe naa le Ryan Giggs to je agbaboolu ati olukoni lati mu egbe naa wa ni igbarad lati koju Norwich ninu ifesewonse ti yoo waye lojo satide.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment