Smiley face

Ijaya Ati Eru Tun Pada Si Ilu Abuja Nigba Ti Tanka Epo Dun Gbamu Lojiji

Jinijni mu awon eniyan ti won n gbe ni agbegbe Asokoro ni ilu Abuja lojo Eti to koja yii nigba ti tanka oko epo kan sadeede lana ti gbogbo e si bere si ni dun gbamugbamu. Opolopo awon eniyan sebi boya awon Boko Haram lo tun pada wolu pelu ara otun ise owo won ni nigba ti isele naa waye ni nnkan bi ago mejo ale.
 
 
Lojiji ni oro di boolo-o-yago lona, eni to wa ninu car sare jade ti won n fese sare lo, baagi olomoge jabo anti Bukky ko duro weyin gbe baagi mo. Awon eniyuan ti sare de igba maili ki oro to ye won wi pe ijamba ina lasan ni kii se bombu lo dun.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment