Baale of Nigeria olorin takasufe ti gbogbo eniyan mo si Tuface ti so fun awon oniroyin wi pe oun ti pari ise oun nipa omo bibi ati wi pe eleyii ti oun ti bi ki Edumare fi alubarika sii. Tuface to ti bimo bi meje pelu orisii obirin meta otooto loni ohun to ku fun oun bayii ni lati maa toju iyawo oun ati awon omo, ko si oun ti n je oro omo bibi ninu oro oun mo. Oro yii lo so ni ilu Ibadan, Ilu Ogunmola nibi iworan kebuyeri alawada ti Gbenga Adeyinka se agbeteru re ti won pe ni Laffmatazz Show
"I am tired of having babies. At this point in my life, I want to show my family all the love and support they deserve. I love my wife and there is not going to be anything like have babies outside wedlock. All I need to do now is to show love to my family and friends who stood by me over the years" Tuface
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment