Smiley face

Arugbo Ojo Da Ogo Arsenal Pada Niwaju Awon Elegan

Egbe agbaboolu Arsenal gbe igba oroke lonii nigba ti won na Hull City sare ninu idije asekagbe F.A Cup ti ilu England.

Odun kesan-an re e ti awon ota egbe agbaboolu Arsenal ti n fi egbe naa se yeye latari wi pe won ko ri ife eye kankan gbe soke.

Sugbo sitori won yato lale oni, nigba ti Arugbo ojo da ogo won pada ni papa isere Wembley nibi ti Arsenal ti ko ayo meta alailabula fun Hull City ti awon naa si gbinyaju lati da meji pada ninu iya meta to je won.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment