Smiley face

Yinka Ayefele Fe Sodun Awon Ewe Ni Ilu Ibadan


Ojo ketadinlogbon osu karun-un odun(27/5/14) eleyii ti won fi n sami ayajo awon omode ni ile Nigeria, ohun ni Yinka Ayefele ti pinnu lati fi dun awon omode ninu pelu opolopo orin, ijo, jije ati mimu ati ere idaraya lorisiirisii.

Ile orin Ayefele (Music House) to wa ni ilu Ibadan naa ni faaji naa yo ti waye. Ofe si ni owo iwole.

Yinka Ayefele ni ki awon omo yin mu polibaagi dani. Nitori ti won ba je ti won yo tan, won a tun di lo sile.

Ayefele N Se Bebe!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment