Smiley face

"Iku Ko Si Loju Mi" -Dora Akunyili

Arabirin Dora Akunyili ni amugbalegbe re ti fi oro sita wi pe oga oun ko ku o, mama n gba itoju lowo ni ni ilu India.

Oro yii lo waye latari aheso oro kan to n lo nigboro aye wi pe Arabirin Dora Akunyili ti keru si koto. Bi o tile je wi pe mama se opolopo aisan, eleyii to mu awon eniyan ma le damo mo sibesibe nnkan ti n pada bo sipo fun un ni ilu India to wa.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment