Enikan lo fi awada kekere yii ranse si mi lori foonu BB mi. Mo ni ki n ma da rerin, eyin naa e gba.
Isorongbesi waye laaarin Ajan ati Abija.
Bo se lo ni yii
Ajan: Aaabiiijaaaaa
Abija: Ajan ooo
Ajan: Se iwo o ri awon omo ti awon. Boko Haram jigbe ni?
Abija: Ajan, mo ri won.
Ajan: Oyaa! Wa lo tu won sile kuro ninu igbekun ti won waaaaa
Abija: TURAYA ni. Iwo naa lo tuwon sile funra e.
Ajan: Emi o le lo nitori pe emi ni mo maa di ile mu de o ti iwo ba lo.
Abija: Ooo ni kuureee! Jaaakuro lori ago funmi jooorr.
Hahahahahahahahahahahaha
0 comments:
Post a Comment