Ninu Ibeere ati Idahun to waye lori ate Twitter MTV ni Ayo ti je ka mo bosenlo gan-an laaarin oun ati iyawo re, Tania nipa ohun to fa sababi iyapa won. Ibrahim ko soro pupo, o ni ko si idi kankan ju wi pe oun ko ti setan fun igbeyawo bayii.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment