Smiley face

Awon Baalu Oloju Ina Merindinlogun Ti Wo Ilu Nigeria Pelu Agbara Nla

Ilu Amerika ti wo ilu Nigeria pelu Baalu oloju ina merindinlogun lati wa awon omobirin bi igba ti Boko Haram jigbe salo. E gbo ohun ti awon alase alaabo ile Amerika wi:

“We have shared commercial satellite imagery with the Nigerians and are flying manned ISR (intelligence, surveillance and reconnaissance) assets over Nigeria with the government’s permission.” 

Iroyin to tun te wa lowo bayii ni wi pe awon baalu alagbara oloju ina merindinlogun tile ti foju kan awon omobirin bi ogofa ninu igbo ti Boko Haram ko won pamo si nikete ti won bere ise won loju ofurufu ile Nigeria.

“Our intelligence experts are combing through every detail of the video for clues that might help ongoing efforts to secure the release of the girls,” Jen Psaki 

Agbenuso ile Amerika tun fi da awon oniroyin loju wi pe ise awon dawon loju gbangba nipa wi pe awon ti ri awon omo naa.

“We have no reason to question its authenticity.'

Jen Psaki  to n gbenuso fun ile Amerika tun fi ye wa wi pe awon ko ni gba ki Boko Haram gba ohunkohun lowo Nigeria titi awon yoo fi yanju gbogbo oro naa patapata.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment