Smiley face

Se Iro Ni Oro Yii Abi Ododo?

Bi awon kan se n pariwo #BringBackOurGirls sibesiibe awon kan si lero wi pe arummoje lasan ni gbogbo isele ti won  lo sele. Nje a le so wi pe iro ni wi pe Boko Haram ji awon omobirin bi igba gege bi iroyin to gba gbogbo aye ti wi?


E gbo iforowero to waye laaarin osise ile ise CNN ati okan ninu awon omobirin ti Boko Haram jiko sugbon to pada sa mo won lowo.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment