Smiley face

Okiki Omobirin To N Fi Irun Ori Re Fa Moto


Iwe akosile Guinness Records ti kede Joanna Sawicka omo ilu Biritiko gege bi eni ti irun ori re lagbara ju lagbaye. Ko si ohun ti omobirin naa ko le fi irun ori re fa. Agbara ti Edua oke fun irun ori re naa lo fi n pawo kaakiri agbaye bayii pelu bi gbogbo eniyan se n pe wo iran re nibikibi to ba ti n pidan.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment