Smiley face

Awon Omo Unilag Fe Ku Si Iyanya Lorun

Iyanya la gbo wi pe o lo da won omo Unilag laraya lana ode yii. Lonisuuru ni faaji naa koko fi bere sugbon nigba to ya, ti orin ati ilu wora daada. Iyanya bora sile, awon omo Unilag ba ni awon gan-an wa nile. Ariwo ta lala, eni ti ko moojo n fosoke, awon omoge ti won 'lapoti ijoko' n tadi reke gbogbo  si n dun yin-in.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment