Smiley face

Chelsea Ti Ko Ba Peter Okoye (P-square)


Ololufe egbe agbaboolu Chelsea ni Peter Okoye. Sugbon o padanu owo bi egberun marun-un owo dollar ($5,000) ninu tete to ta pelu akegbe re olorin,Phyno nigba ti egbe agboolu Chelsea fidiremi lana ode yii. Bi o tile je wi pe Chelsea tiraka lati ta omi (0-0) ni ilu Spain sugbon nnkan ko senu ire nigba ti Atletico Madrid ka won mole pelu ayo meta si ookan. 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment