Nibi ayeye ayajo awon ewe to waye lana ni ile ijoba apapo to wa l'Abuja ni aya Aare ile Nigeria, Patience Jonathan ti gbogbo eniyan tun pe ni Mama Peace ti je ko ye awon eniyan wi pe eebu ati awon oro alufansa ti won fi n ranse si oko oun ko le help matter rara.
Gege bi oro re, o ni Olorun oba lo fi si ori oye o si di dandan fun gbogbo wa lati se aponle fun-un.
Die lara oro Mama Peace ni yii:
"It is bad to abuse our country and the President because God has made him the head.
"The Almighty God commands us to pray for our leaders. We therefore need to pray for the development of our country and the President."
0 comments:
Post a Comment